Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 94:12-14 BIBELI MIMỌ (BM)

12. Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí o bá báwí, OLUWA,tí o sì kọ́ ní òfin rẹ,

13. kí ó lè sinmi lọ́wọ́ ọjọ́ ìṣòro,títí tí a ó fi gbẹ́ kòtò fún eniyan burúkú.

14. Nítorí OLUWA kò ní kọ àwọn eniyan rẹ̀ sílẹ̀;kò ní ṣá àwọn eniyan ìní rẹ̀ tì;

Ka pipe ipin Orin Dafidi 94