Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 94:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA, ìwọ Ọlọrun ẹ̀san,ìwọ Ọlọrun ẹ̀san, fi agbára rẹ hàn!

2. Dìde, ìwọ onídàájọ́ ayé;san ẹ̀san èrè iṣẹ́ àwọn agbéraga fún wọn!

Ka pipe ipin Orin Dafidi 94