Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 83:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọlọrun, má dákẹ́;má wòran; Ọlọrun má dúró jẹ́ẹ́!

2. Wò ó! Àwọn ọ̀tá rẹ ń ṣọ̀tẹ̀ sí ọ;àwọn tí ó kórìíra rẹ sì ń yájú sí ọ.

3. Wọ́n pète àrékérekè sí àwọn eniyan rẹ;wọ́n sì gbìmọ̀ pọ̀ sí àwọn tí ó sá di ọ́.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 83