Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 78:55 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde kí wọn ó tó dé ibẹ̀;ó pín ilẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè fún wọn bí ohun ìní;ó sì fi àwọn ọmọ Israẹli jókòó ninu àgọ́ wọn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 78

Wo Orin Dafidi 78:55 ni o tọ