Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 77:19-20 BIBELI MIMỌ (BM)

19. Ọ̀nà rẹ wà lójú omi òkun,ipa ọ̀nà rẹ la omi òkun ńlá já;sibẹ ẹnìkan kò rí ipa ẹsẹ̀ rẹ.

20. O kó àwọn eniyan rẹ jáde bí agbo ẹran,o fi Mose ati Aaroni ṣe olórí wọn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 77