Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 76:11-12 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún OLUWA Ọlọrun rẹ, kí o sì mú un ṣẹ,kí gbogbo àwọn tí ó yí i ká mú ẹ̀bùn wáfún ẹni tí ó yẹ kí á bẹ̀rù.

12. Ẹni tí ń gba ẹ̀mí àwọn ìjòyè,tí ó ń ṣe ẹ̀rù ba àwọn ọba ayé.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 76