Ọlọrun yóo gba gbogbo agbára ọwọ́ àwọn eniyan burúkú kúrò;ṣugbọn yóo fi agbára kún agbára fún àwọn olódodo.