Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 7:16-17 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Ìkà rẹ̀ pada sórí ara rẹ̀,àní ìwà ipá rẹ̀ sì já lù ú ní àtàrí.

17. N óo fi ọpẹ́ tí ó yẹ fún OLUWA nítorí òdodo rẹ̀,n óo fi orin ìyìn kí OLUWA, Ọ̀gá Ògo.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 7