Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 69:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Gbà mí, Ọlọrun,nítorí omi ti mù mí dé ọrùn.

2. Mo ti rì sinu irà jíjìn,níbi tí kò ti sí ohun ìfẹsẹ̀tẹ̀;mo ti bọ́ sinu ibú,omi sì ti bò mí mọ́lẹ̀.

3. Mo sọkún títí àárẹ̀ mú mi,ọ̀nà ọ̀fun mi gbẹ,ojú mi sì di bàìbàì,níbi tí mo ti dúró, tí mò ń wo ojú ìwọ Ọlọrun mi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 69