Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 67:5-7 BIBELI MIMỌ (BM)

5. Jẹ́ kí àwọn eniyan ó máa yìn ọ́, Ọlọrun;jẹ́ kí gbogbo eniyan máa yìn ọ́!

6. Ilẹ̀ mú ọ̀pọ̀ ìkórè jáde;Ọlọrun, àní Ọlọrun wa, bukun wa.

7. Ọlọrun bukun wa,kí gbogbo ayé máa bẹ̀rù rẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 67