Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 67:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Kí Ọlọrun óo ṣàánú wa, kí ó bukun wa;kí ojú rẹ̀ tan ìmọ́lẹ̀ sí wa lára;

2. kí gbogbo ayé lè mọ ọ̀nà rẹ̀;kí gbogbo orílẹ̀-èdè sì mọ ìgbàlà rẹ̀.

3. Jẹ́ kí àwọn eniyan ó máa yìn ọ́, Ọlọrun;jẹ́ kí gbogbo eniyan máa yìn ọ́!

Ka pipe ipin Orin Dafidi 67