Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 65:12-13 BIBELI MIMỌ (BM)

12. Gbogbo pápá oko kún fún ẹran ọ̀sìn,àwọn ẹ̀gbẹ́ òkè sì kún fún ohun ayọ̀,

13. ẹran ọ̀sìn bo pápá oko bí aṣọ,ọkà bo gbogbo àfonífojì, ó sì so jìngbìnnì,wọ́n ń hó, wọ́n sì ń kọrin ayọ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 65