Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 65:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọlọrun, ìwọ ni ìyìn yẹ ní Sioni,ìwọ ni a óo san ẹ̀jẹ́ wa fún,

2. ìwọ tí ń gbọ́ adura!Ọ̀dọ̀ rẹ ni gbogbo eniyan ń bọ̀,

Ka pipe ipin Orin Dafidi 65