Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 63:9-11 BIBELI MIMỌ (BM)

9. Ṣugbọn àwọn tí ń wá ọ̀nà láti gba ẹ̀mí miyóo sọ̀kalẹ̀ lọ sinu isà òkú.

10. A ó fi idà pa wọ́n lójú ogun,ẹranko ni yóo sì jẹ òkú wọn.

11. Ṣugbọn ọba yóo máa yọ̀ ninu Ọlọrun;gbogbo àwọn tí ń fi orúkọ OLUWA búrayóo máa fògo fún un;ṣugbọn a ó pa àwọn òpùrọ́ lẹ́nu mọ́.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 63