Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 60:11-12 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Ràn wá lọ́wọ́, bá wa gbógun ti àwọn ọ̀tá wa,nítorí pé asán ni ìrànlọ́wọ́ eniyan.

12. Pẹlu àtìlẹ́yìn Ọlọrun a óo ṣe akin,nítorí òun ni yóo tẹ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 60