Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 6:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA, má fi ibinu bá mi wí;má sì fi ìrúnú jẹ mí níyà.

2. Ṣàánú mi, OLUWA, nítorí àárẹ̀ mú ọkàn mi,OLUWA, wò mí sàn nítorí ara ń ni mí dé egungun.

3. Ọkàn mi kò balẹ̀ rárá,yóo ti pẹ́ tó, OLUWA, yóo ti pẹ́ tó?

Ka pipe ipin Orin Dafidi 6