Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 57:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣàánú mi, Ọlọrun, ṣàánú mi,nítorí ìwọ ni ààbò mi;abẹ́ òjìji apá rẹ ni n óo fi ṣe ààbò mi,títí gbogbo àjálù wọnyi yóo fi kọjá.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 57

Wo Orin Dafidi 57:1 ni o tọ