Ọlọrun bojú wo àwọn ọmọ eniyan láti ọ̀run wá,ó ń wò ó bí àwọn kan bá wà tí òye yé,àní, bí àwọn kan bá wà tí ń wá Ọlọrun.