Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 5:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn jẹ́ kí inú gbogbo àwọn tí ó sá di ọ́ ó dùn,kí wọn ó máa kọrin ayọ̀ títí lae.Dáàbò bò wọ́n,kí àwọn tí ó fẹ́ràn orúkọ rẹ sì máa yọ̀ ninu rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 5

Wo Orin Dafidi 5:11 ni o tọ