Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 45:7 BIBELI MIMỌ (BM)

O fẹ́ràn òdodo, o sì kórìíra ìwà ìkànítorí náà ni Ọlọrun, àní Ọlọrun rẹ, ṣe fi àmì òróró yàn ọ́.Àmì òróró ayọ̀ ni ó fi gbé ọ gaju àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ lọ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 45

Wo Orin Dafidi 45:7 ni o tọ