Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 44:25-26 BIBELI MIMỌ (BM)

25. Nítorí pé àwọn ọ̀tá ti tẹ̀ wá mọ́lẹ̀;àyà wa sì lẹ̀ mọ́lẹ̀ típẹ́típẹ́.

26. Gbéra nílẹ̀, kí o ràn wá lọ́wọ́!Gbà wá sílẹ̀ nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 44