Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 43:4-5 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Nígbà náà ni n óo lọ sí ibi pẹpẹ Ọlọrun,àní, sọ́dọ̀ Ọlọrun, ayọ̀ ńlá mi.Èmi óo sì yìn ọ́ pẹlu hapu,Ọlọrun, Ọlọrun mi.

5. Ìwọ ọkàn mi, kí ló dé tí o fi rẹ̀wẹ̀sì?Kí ló dé tí ara rẹ kò fi balẹ̀ ninu mi?Gbẹ́kẹ̀ rẹ lé Ọlọrun; nítorí pé n óo tún yìn ín,olùrànlọ́wọ́ mi ati Ọlọrun mi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 43