Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 37:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú OLUWA; fi sùúrù gbẹ́kẹ̀lé e.Má gbé ara rẹ lọ́kàn gbóná nítorí ẹni tí nǹkan ń dára fún;tabi nítorí ẹni tí ń gbèrò ibi, tí ó sì ń ṣe é.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 37

Wo Orin Dafidi 37:7 ni o tọ