Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 29:9-11 BIBELI MIMỌ (BM)

9. Ohùn OLUWA a máa mú abo àgbọ̀nrín bí,a máa wọ́ ewé lára igi oko;gbogbo eniyan ń kígbe ògo rẹ̀ ninu Tẹmpili rẹ̀.

10. OLUWA jókòó, ó gúnwà lórí ìkún omi;OLUWA jókòó, ó gúnwà bí ọba títí lae.

11. OLUWA yóo fún àwọn eniyan rẹ̀ ní agbára;OLUWA yóo fún wọn ní ibukun alaafia.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 29