Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 24:8-10 BIBELI MIMỌ (BM)

8. Ta ni Ọba ògo yìí?OLUWA tí ó ní ipá tí ó sì lágbára,OLUWA tí ó lágbára lógun.

9. Ẹ ṣí sílẹ̀ gbayau, ẹ̀yin ìlẹ̀kùn,ẹ wà ní ṣíṣí sílẹ̀, ẹ̀yin ìlẹ̀kùn ayérayé,kí Ọba ògo lè wọlé.

10. Ta ni Ọba ògo yìí?OLUWA àwọn ọmọ ogun,òun ni Ọba ògo náà.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 24