Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 21:11-13 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Bí wọn bá gbèrò ibi sí ọ,tí wọ́n sì pète ìkà, wọn kò ní lè ṣe é.

12. Nítorí pé o óo lé wọn sá;nígbà tí o bá fi ọfà rẹ sun ojú wọn.

13. A gbé ọ ga, nítorí agbára rẹ, OLUWA!A óo máa kọrin, a óo sì máa yin agbára rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 21