Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 21:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọba ń yọ̀ nítorí agbára rẹ, OLUWA;inú rẹ̀ ń dùn lọpọlọpọ nítorí ríràn tí o ràn án lọ́wọ́!

2. O ti fún un ní ohun tí ọkàn rẹ̀ ń fẹ́,o kò sì fi ohun tí ó ń tọrọ dù ú.

3. O gbé ibukun dáradára pàdé rẹ̀;o fi adé ojúlówó wúrà dé e lórí.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 21