Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 2:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Kí ló dé tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń bínú fùfùtí àwọn eniyan ń gbìmọ̀ asán?

2. Àwọn ọba ayé kó ara wọn jọ,àwọn ìjòyè gbìmọ̀ pọ̀,wọ́n dojú kọ OLUWA ati àyànfẹ́ rẹ̀.

3. Wọn ń wí pé, “Ẹ jẹ́ kí á fa ẹ̀wọ̀n tí wọ́n fi dè wá jákí á sì yọ ara wa kúrò lóko ẹrú wọn.”

Ka pipe ipin Orin Dafidi 2