Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 18:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ni àpáta mi, ibi ààbò mi, ati olùgbàlà mi;Ọlọrun mi, àpáta mi, ninu ẹni tí ààbò mi wà.Òun ni asà mi, ìwo ìgbàlà mi ati ibi ìsásí mi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 18

Wo Orin Dafidi 18:2 ni o tọ