Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 18:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá mi tí ó lágbára,ati lọ́wọ́ àwọn tí ó kórìíra mi;nítorí wọ́n lágbára jù mí lọ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 18

Wo Orin Dafidi 18:17 ni o tọ