Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 17:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dàbí kinniun tí ó ṣetán láti pa ẹran jẹ,àní bí ọmọ kinniun tí ó ba ní ibùba.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 17

Wo Orin Dafidi 17:12 ni o tọ