Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 150:4-6 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Ẹ fi ìlù ati ijó yìn ín;ẹ fi gòjé ati dùùrù yìn ín.

5. Ẹ fi aro olóhùn òkè yìn ín;ẹ fi aro olóhùn gooro yìn ín.

6. Kí gbogbo nǹkan ẹlẹ́mìí yin OLUWA! Ẹ yin OLUWA!

Ka pipe ipin Orin Dafidi 150