Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 150:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ yin OLUWA!Ẹ yin Ọlọrun ninu ibi mímọ́ rẹ̀;ẹ yìn ín ninu òfuurufú rẹ̀ tí ó lágbára.

2. Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ ńlá rẹ̀;ẹ yìn ín nítorí pé ó tóbi pupọ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 150