Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 149:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ yin OLUWA!Ẹ kọ orin titun sí OLUWA,ẹ kọrin ìyìn sí i ninu àwùjọ àwọn olóòótọ́.

2. Kí Israẹli máa yọ̀ ninu Ẹlẹ́dàá rẹ̀,kí àwọn ọmọ Sioni máa fò fún ayọ̀ pé àwọn ní Ọba.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 149