Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 147:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ yin OLUWA!Nítorí tí ó dára láti máa kọ orin ìyìn sí Ọlọrun wa;nítorí olóore ni, orin ìyìn sì yẹ ẹ́.

2. OLUWA ní ń kọ́ ìlú Jerusalẹmu;òun ni yóo kó àwọn ọmọ Israẹli tí a fọ́n ká jọ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 147