Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 139:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí à ń ṣẹ̀dá egungun mi lọ́wọ́ ní ìkọ̀kọ̀,tí ẹlẹ́dàá ṣẹ̀ṣẹ̀ ń ṣọnà sí mi lára ní àṣírí,kò sí èyí tí ó pamọ́ fún ọ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 139

Wo Orin Dafidi 139:15 ni o tọ