Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 132:6-8 BIBELI MIMỌ (BM)

6. A gbúròó rẹ̀ ní Efurata,a rí i ní oko Jearimu.

7. “Ẹ jẹ́ kí á lọ sí ibùgbé rẹ̀;ẹ jẹ́ kí á lọ wólẹ̀ níbi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀.”

8. Dìde, OLUWA, lọ sí ibi ìsinmi rẹ,tìwọ ti àpótí agbára rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 132