Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 128:4-6 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Wò ó, bẹ́ẹ̀ ni OLUWA yóo kẹ́ ẹni tí ó bẹ̀rù rẹ̀.

5. Kí OLUWA bukun ọ láti Sioni!Kí o máa rí ire Jerusalẹmuní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.

6. Kí o máa rí arọmọdọmọ rẹ.Kí alaafia máa wà ní Israẹli.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 128