Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 128:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó bẹ̀rù OLÚWA,tí ó sì ń tẹ̀lé ìlànà rẹ̀.

2. O óo jèrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ,ayọ̀ ń bẹ fún ọ, yóo sì dára fún ọ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 128