Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 126:1-4 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Nígbà tí OLUWA kó àwọn ìgbèkùn Sioni pada,ó dàbí àlá lójú wa.

2. Ẹ̀rẹ̀kẹ́ wa kún fún ẹ̀rín, a sì kọrin ayọ̀,nígbà náà ni àwọn orílẹ̀-èdè yòókù ń wí pé,“OLUWA mà ṣe nǹkan ńlá fún àwọn eniyan yìí!”

3. Lóòótọ́, OLUWA ṣe nǹkan ńlá fún wa, nítorí náà à ń yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀.

4. Dá ire wa pada, OLUWA,bí ìṣàn omi ní ipadò aṣálẹ̀ Nẹgẹbu.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 126