Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 125:1-4 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLUWA dàbí òkè Sioni,tí ẹnikẹ́ni kò lè ṣí nídìí, ṣugbọn tí ó wà títí lae.

2. Bí òkè ńlá ti yí Jerusalẹmu ká,bẹ́ẹ̀ ni OLUWA yí àwọn eniyan rẹ̀ ká,láti ìsinsìnyìí lọ ati títí lae.

3. Eniyan burúkú kò ní ní àṣẹlórí ilẹ̀ àwọn olódodo,kí àwọn olódodo má baà dáwọ́ lé ibi.

4. OLUWA, ṣe oore fún àwọn eniyan rere,ati fún àwọn olódodo.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 125