Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 122:8-9 BIBELI MIMỌ (BM)

8. Nítorí ti àwọn ará ati àwọn ẹlẹgbẹ́ mi,n óo wí pé, “Kí alaafia ó wà ninu rẹ.”

9. Nítorí ti ilé OLUWA, Ọlọrun wa,èmi óo máa wá ire rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 122