Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 122:7-9 BIBELI MIMỌ (BM)

7. Kí alaafia ó wà ninu rẹ,kí ìbàlẹ̀ àyà wà ninu ilé ìṣọ́ rẹ.”

8. Nítorí ti àwọn ará ati àwọn ẹlẹgbẹ́ mi,n óo wí pé, “Kí alaafia ó wà ninu rẹ.”

9. Nítorí ti ilé OLUWA, Ọlọrun wa,èmi óo máa wá ire rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 122