Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 121:6-8 BIBELI MIMỌ (BM)

6. Oòrùn kò ní ṣe ọ́ léṣe lọ́sàn-án,bẹ́ẹ̀ ni òṣùpá kò ní pa ọ́ lára lóru.

7. OLUWA óo dáàbò bò ọ́ lọ́wọ́ gbogbo ibi,yóo pa ọ́ mọ́.

8. OLUWA yóo pa àlọ ati ààbọ̀ rẹ mọ́,láti ìsinsìnyìí lọ ati títí lae.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 121