Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 121:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Mo gbójú sókè wo àwọn òkè,níbo ni ìrànlọ́wọ́ mi ti ń wá?

2. Ìrànlọ́wọ́ mi ń ti ọ̀dọ̀ OLUWA wá,ẹni tí ó dá ọ̀run ati ayé.

3. Kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ ó yẹ̀,ẹni tí ń pa ọ́ mọ́ kò ní tòògbé.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 121