Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 12:6-8 BIBELI MIMỌ (BM)

6. Ìlérí tó dájú ni ìlérí OLUWA,ó dàbí fadaka tí a yọ́ ninu iná ìléru amọ̀,tí a dà ninu iná nígbà meje.

7. Dáàbò bò wá, OLUWA, pa wá mọ́ laelaekúrò lọ́wọ́ irú àwọn eniyan báwọ̀nyí.

8. Àwọn eniyan burúkú ń yan kiri,níwọ̀n ìgbà tí àwọn eniyan ń ṣe àpọ́nlé iṣẹ́ ibi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 12