Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 119:18-21 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Là mí lójú, kí n lè rí àwọn nǹkan ìyanutí ó wà ninu òfin rẹ.

19. Àlejò ni mí láyé,má fi òfin rẹ pamọ́ fún mi.

20. Òùngbẹ títẹ̀lé òfin rẹ ń gbẹ ọkàn mi, nígbà gbogbo.

21. O bá àwọn onigbeeraga wí, àwọn ẹni ègún,tí wọn kò pa òfin rẹ mọ́.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 119