Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 119:174-176 BIBELI MIMỌ (BM)

174. Ọkàn mi ń fà sí ìgbàlà rẹ, OLUWA;òfin rẹ sì ni inú dídùn mi.

175. Dá mi sí kí n lè máa yìn ọ́,sì jẹ́ kí òfin rẹ ràn mí lọ́wọ́.

176. Mo ti ṣìnà bí aguntan tó sọnù;wá èmi, iranṣẹ rẹ, rí,nítorí pé n kò gbàgbé òfin rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 119