Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 119:153-155 BIBELI MIMỌ (BM)

153. Wo ìpọ́njú mi, kí o gbà mí,nítorí n kò gbàgbé òfin rẹ.

154. Gba ẹjọ́ mi rò, kí o sì gbà mí,sọ mí di alààyè gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ.

155. Ìgbàlà jìnnà sí àwọn eniyan burúkú,nítorí wọn kò wá ìlànà rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 119