Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 119:12-16 BIBELI MIMỌ (BM)

12. Ìyìn ni fún ọ, OLUWA,kọ́ mi ní ìlànà rẹ!

13. Mo fi ẹnu mi kéde gbogbo àṣẹ tí o pa.

14. Mo láyọ̀ ninu pípa òfin rẹ mọ́,bí ẹni tí ó ní ọpọlọpọ ọrọ̀.

15. N óo máa ṣe àṣàrò ninu òfin rẹ,n óo sì kọjú sí ọ̀nà rẹ.

16. N óo láyọ̀ ninu àwọn ìlànà rẹ,n kò ní gbàgbé ọ̀rọ̀ rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 119